The Bible › Bíbélì Mímọ́ › Mark 9

Mark 9:48

Níbi ti “ ‘kòkòrò wọn kì í kú, tí iná kì í sì í kú.’

Mark 9:48 · Bíbélì Mímọ́

← PreviousRead Mark 9Next →

Mark 9:48 in other translations

KJV King James Version

Where their worm dieth not, and the fire is not quenched.

BSB Berean Standard Bible

where ‘their worm never dies, and the fire is never quenched.’

WEB World English Bible

‘where their worm doesn’t die, and the fire is not quenched.’

Every translation above is public domain and free to share. Other versions — NIV · ESV · NKJV · NLT · NASB · CSB · AMP — are copyrighted and open on their publishers’ partner site.

In context

45 Bí ẹsẹ̀ rẹ bá sì mú ọ kọsẹ̀, gé é sọnù, ó sàn kí ó di akesẹ̀, kí o sì gbé títí ayé àìnípẹ̀kun ju kí o ní ẹsẹ̀ méjì tí ó gbé ọ lọ sí ọ̀run àpáàdì.

47 Bí ojú rẹ bá sì mú ọ kọsẹ̀, yọ ọ́ sọnù, ó sàn kí o wọ ìjọba Ọlọ́run pẹ̀lú ojú kan ju kí ó ní ojú méjì kí ó sì lọ sínú iná ọ̀run àpáàdì.

48 Níbi ti “ ‘kòkòrò wọn kì í kú, tí iná kì í sì í kú.’

49 Níbẹ̀ ni a ó ti fi iná dán ẹnìkọ̀ọ̀kan wò.

50 “Iyọ̀ dára, ṣùgbọ́n tí ó bá sọ adùn rẹ̀ nù, báwo ni ẹ ṣè lè padà mú un dùn? Ẹ ni iyọ̀ nínú ara yín, ki ẹ sì máa gbé ní àlàáfíà pẹ̀lú ara yín.”

Read Mark 9 in the app The whole chapter

Search the Scriptures

Choose a translation

KJVBSBWEBNHEBASVYLTDBYWBTBBEEBRGNVDRALUTCANRIVLSGRVABPMYORIGBSWATGLIRV