The Bible › Bíbélì Mímọ́ › Matthew 22

Matthew 22:39

Èkejì tí ó tún dàbí rẹ̀ ní pé, ‘Fẹ́ràn ọmọnìkejì rẹ gẹ́gẹ́ bí ara rẹ.’

Matthew 22:39 · Bíbélì Mímọ́
Why this verse matters. And the second is like it. Jesus says the whole law and the prophets hang on these two.

← PreviousRead Matthew 22Next →

Matthew 22:39 in other translations

KJV King James Version

And the second is like unto it, Thou shalt love thy neighbour as thyself.

BSB Berean Standard Bible

And the second is like it: ‘Love your neighbor as yourself.’

WEB World English Bible

A second likewise is this, ‘You shall love your neighbor as yourself.’

Every translation above is public domain and free to share. Other versions — NIV · ESV · NKJV · NLT · NASB · CSB · AMP — are copyrighted and open on their publishers’ partner site.

In context

36 Ó wí pé, “Olùkọ́ èwo ni ó ga jùlọ nínú àwọn òfin?”

37 Jesu dáhùn pé, “ ‘Fẹ́ Olúwa Ọlọ́run rẹ pẹ̀lú gbogbo ọkàn rẹ, gbogbo ẹ̀mí rẹ àti gbogbo inú rẹ.’

38 Èyí ni òfin àkọ́kọ́ àti èyí tí ó tóbi jùlọ.

39 Èkejì tí ó tún dàbí rẹ̀ ní pé, ‘Fẹ́ràn ọmọnìkejì rẹ gẹ́gẹ́ bí ara rẹ.’

40 Lórí àwọn òfin méjèèjì yìí ni gbogbo òfin àti àwọn wòlíì rọ̀ mọ́.”

41 Bí àwọn Farisi ti kó ara wọn jọ, Jesu béèrè lọ́wọ́ wọn pé,

42 “Kí ni ẹ rò nípa Kristi? Ọmọ ta ni òun ń ṣe?” Wọ́n dáhùn pé, “Ọmọ Dafidi.”

Read Matthew 22 in the app The whole chapter

Search the Scriptures

Choose a translation

KJVBSBWEBNHEBASVYLTDBYWBTBBEEBRGNVDRALUTCANRIVLSGRVABPMYORIGBSWATGLIRV