The Bible › Bíbélì Mímọ́ › Exodus 6

Exodus 6:21

Àwọn ọmọ Isari ni: Kora, Nefegi àti Sikri.

Exodus 6:21 · Bíbélì Mímọ́

← PreviousRead Exodus 6Next →

Exodus 6:21 in other translations

KJV King James Version

And the sons of Izhar; Korah, and Nepheg, and Zichri.

BSB Berean Standard Bible

The sons of Izhar were Korah, Nepheg, and Zichri.

WEB World English Bible

The sons of Izhar: Korah, and Nepheg, and Zichri.

Every translation above is public domain and free to share. Other versions — NIV · ESV · NKJV · NLT · NASB · CSB · AMP — are copyrighted and open on their publishers’ partner site.

In context

18 Àwọn ọmọ Kohati ni: Amramu, Isari, Hebroni àti Usieli. Kohati lo ẹ̀tàléláádóje (133) ọdún láyé.

19 Àwọn ọmọ Merari ni: Mahili àti Muṣi. Ìwọ̀nyí ni ìran Lefi gẹ́gẹ́ bí àkọsílẹ̀ wọn.

20 Amramu sì fẹ́ Jokebedi arábìnrin baba rẹ̀ ní ìyàwó. Jokebedi sì bí Aaroni àti Mose fún un. Amramu lo ẹ̀tàdínlógóje (137) ọdún láyé.

21 Àwọn ọmọ Isari ni: Kora, Nefegi àti Sikri.

22 Àwọn ọmọ Usieli ni: Miṣaeli, Elsafani àti Sitiri.

23 Aaroni fẹ́ Eliṣeba ọmọbìnrin Amminadabu tí í ṣe arábìnrin Nahiṣoni, ó sì bí Nadabu, Abihu, Eleasari àti Itamari.

24 Àwọn ọmọ Kora ni: Asiri, Elkana àti Abiasafu. Ìwọ̀nyí ni ìran Kora.

Read Exodus 6 in the app The whole chapter

Search the Scriptures

Choose a translation

KJVBSBWEBNHEBASVYLTDBYWBTBBEEBRGNVDRALUTCANRIVLSGRVABPMYORIGBSWATGLIRV